Home / Àṣà Oòduà / Iwe Iroyin Owuro ose yii kun fofo bi ataare

Iwe Iroyin Owuro ose yii kun fofo bi ataare


Ti eyin ko ba tii ra iwe Iroyin Owuro to jade lose yii, a je wi pe iroyin ku sibi kan te e ti gbo.

Lati ori oro oselu de amuludun, awon oro to n lo ati igbelaruge asa ati ise Yoruba; gbogbo re lo kun fofo bi ataare.

Die ni yii lara awon koko iroyin to jade:

*Orangun yari mo Aregbe ati Owa Obokun lowo

*Alison-Madueke ko si panpe Buhari niluu London

*”Ijoba ibile wa kii fun Tinubu ni owo kankan”- Alaga kansu lo so bee

*Odun Ominira: Okan awon omo Naijiria tun taji si orileede won.

*”Obe didun ati ere ori beedi ni mo maa fi n mu oko mi mole” – Ronke Osodi-Oke

E ra iwe Iroyin Owuro ti ose yii lati ka awon ojulowo iroyin yii ati awon mii. Ogorun-un naira pere ni. Aye gbogbo wa yoo toro bi omi a fowuro pon o. Amin #IroyinOwuro deeeee!

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo