NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
21 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Tiwa Savage gbégbà orókè níbi àmì èye AFRIMA 2017 tí ó sì gba èye náà mó Yemi Alade lówó .

  • November 14, 2017
  • 1 min read
  • 8 Views
Tiwa Savage gbégbà orókè níbi  àmì èye AFRIMA 2017 tí ó sì gba èye náà mó Yemi Alade lówó .

    Òdóbìnrin olórin àkókó ní ikò Marvins , Tiwa Savage gbé igbá orókè ní ibi àmì èye AFRIMA ti odún yí gégé obìnrin àkókó ní ikò adúláwò ti odún yí.

Tiwa Savage pa Yemi Alade, Aramide àti Seyi Shey láyò.

About Author

Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *