Home / Iroyin Pajawiri / Ẹ kú ojúmọ́ Ọjọ́bọ̀ tòní o!
pankere

Ẹ kú ojúmọ́ Ọjọ́bọ̀ tòní o!

Àwòrán Ogbè Ìwẹ̀yìn wa tòní rè, ẹ jẹ́ kí á rántí àwọn Olùkọ́ tí wọ́n máa ń kó pankẹ́rẹ́ bí ẹni tí ń tẹ̀lé Eégún. Kí lorúkọ Olùkọ́ yín tó máa ń gbé pankẹ́rẹ́ kiri nílé ẹ̀kọ́ Ṣẹ́kọ́ńdírì tí ẹ lọ?

About asatiwa

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

kabiyesi

Èyí wuyì àbí kò wuyì?

Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára