Bàbà wá Lérè paimo pé ọgọ́rin ọdún lónìí (80)


Ẹ jẹ ka jọ gbadura fun Ẹda Onile-ọla pe bi wọn ṣe ṣe tọdun yii ni wọn yoo ṣe tẹẹmi-in towo-tọmọ, ninu ilera pipe ati aiku ti i ṣe baalẹ ọrọ.

Comments

One response to “Bàbà wá Lérè paimo pé ọgọ́rin ọdún lónìí (80)”

  1. Mubashir Opeyemi avatar

    Kemi ola ogun oooo
    Aseyi se aimoye odun laye