Home / Àṣà Oòduà / Alibaba tako Anthony Joshua nígbà tí ó ya àwòrán Láì wo aso tí àwon èyà ara rè sì hàn.

Alibaba tako Anthony Joshua nígbà tí ó ya àwòrán Láì wo aso tí àwon èyà ara rè sì hàn.

Anthony Joshua ní láti gbáradì fún ogun míràn báyìí ni Alibaba tí Ó jé apanilérìn-ín àti adérìn-ín pa òsónú se so nígbà tí Anthony fi aya rè hàn tí èyí sì fi hàn wípé okùnrin mésàn-án ni, òun náà sì ya àwòrán ara rè hàn wípé kí Anthony Joshua gbáradì nítorí òun yóò se tán títí odún méjì.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?