Home / Àṣà Oòduà / Iroyin Ere Idaraya Lerefee (02-04-2016)

Iroyin Ere Idaraya Lerefee (02-04-2016)

Ajo to n mojuto ‪#‎LEAGUE‬ awon obinrin nile wa “NWFL kede ola ojo keji osu kerin gege bi ojo ti idije boolu LEAGUE obinrin fun saa tuntun yoo gberaso kaakiri ile wa.
………..
Emi ati awon agbaboolu mi nlo si orile-ede ‪#‎JORDAN‬ lati loo gba ife-eye agbaye fun ile wa NIGERIA ni—————— ‪#‎BALAH_NKIYU‬ lo so bee
…………
‪#‎Ajo_FIFA‬ gbegile Agbeyin iko ‪#‎SUNDERLAND‬ iyen ‪#‎EMMANUEL_EBUE‬ leyin lati maa kopa lori papa fun odun kan gbako ninu ere boolu latari bi o se ko lati sanwo fun Oniduro re “AGENT”
…………..
O yeki ‪#‎PAUL_POGBA‬ ju Ogorun-milionu-pohun owo ile-okere ” £100m pounds” lo ti iko ‪#‎JUVENTUS‬ ba fe taa ————————— ‪#‎ANDREI_PIRLO‬ lo so bee
……………..
Iko ‪#‎LIVEROOL‬ si n foju sona lati ra Atama-tase “STRKER” tuntun iyen lati inu idije ‪#‎GERMAN_BUDISLIGA‬ —————————– ‪#‎JUDGEN_KLOP‬ (Olukoni ‪#‎LIVERPOOL‬ ) Lo so bee..
……………..
Iko ‪#‎BARCELONIA‬ si ni iko to see ni igbekele-julo kaakiri agbaye ———*****————— ‪#‎HENRY_THIENRY‬ lo so bee…
……………
Gbigba ise lowo ‪#‎GARRY_NEVIELE‬ gege bi Olukoni ‪#‎VALENCIA‬ ko bojumu to————————— ‪#‎SIR_ALEX_FERGUSON‬ lo so bee…
………………
FRANK LAMPARD : O maa nira fun ‪#‎CONTE‬ ni saa to nbo lati tuko iko egbe-agbaboolu ‪#‎CHELSEA‬ …
………….
Mo si ni igbagbo kikun pe a si lee gba ife-eye ‪#‎EPL‬ ni saa yii————————— ‪#‎ARSENE_WENGER‬ ( Olukoni ‪#‎ARSENAL‬ ) Lo so bee

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo