Home / Àṣà Oòduà / Yanju Adegboyega: Ohun ti won wi ti ko koreeti”

Yanju Adegboyega: Ohun ti won wi ti ko koreeti”

“Nje e mo pe “oye to kan ara Iwo, o n bo wa kan ara Ede, tawon kan maa n wi yen ko koreeti?

Ilu kan n be ni ka to de Ede ti won n pe “Awo”, ilu yii ni ibujokoo ijoba ibile Egbedore nipinle Osun.

Oye to kan ara “Awo” n bo wa kan ara “Ede” ni won n wi”. – Yanju Adegboyega

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?