Home / Àṣà Oòduà / E fura ooo!!

E fura ooo!!

Eyi ni lati sofun yin wipe anwa arakunrin kan ti oruko re nje Mukaila,ti o je onisowo eran maalu ni onibuore ni agbegbe iyana church ni ilu Ibadan.
Kidnappers
Arakunrin yi ni awon kan pe lati ori ero ilewo re lati bii ojo marun seyin,wipe kowa bawon ra eran maalu,won si gbe si inu motor won,lati ojo naa ao tii foju kan okunrin naa titi di wakaati yi. Mo gba lase ki Eledumare bawa wa okunrin naa ri ooo.Koluwa maa so wa

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...