Àṣà Oòduà
Ase !!
Ase Oriwa konibabode…..Ogbo Ato lankira ni’ledi……Ogun Lakaaye adowo fomo Awo
E gbo kinni yato laarin oloodumare ati Eledumare?
Obi awe kan aje de oyo, baba kukuru de fila bentigo, kini nboba jeun ti kii mu sibi dani? Aguntan baba mi kan lailai, aguntan baba mi kan lailai, owoo ni nje kii je agbado. ( Ahon, oko, esin-sin, Obinrin) happy xmas ni gbogbo kaaro oojire.