Author: oodua
-
Ejo se ebi omo ni abi ti baba
Baba kan wa obi omo kan kunrin kan osope omo ohun kogbodo losi puplic school nitori ko le gbo oyinbo dada baba yii ni alejo ni ojo kan osofun omo yii ko lobu omi wa baba unba ore re soro nigba ti omo bomi de oso fun baba wipe omi re oo baba sope gbe lemi lori be ni omo ba da omi le baba lori ejo ta lo jebi -
Eji Ogbe Verse
Jọ̀gbọ̀dọ̀ lẹ̀fọ́ lorúko ti Ifá ńjẹ́
Ẹ̀rọ̀ wọ̀ loyèe tẹ̀tẹ̀Ayé kọpá
Ẹ̀sọ̀ lo gbàÈle tán láye
Ẹ̀rò ló kùA dífá fún Ìrókò Ẹlujù
Tí wọ́n ní ó máa so okùn
Kó tún máa so oyindẹÌrókò kó o má so èle
Ẹ̀rọ̀ were nÌrókò ń so
Ẹ̀rọ.Courtesy: Moyo Okedeji





