Hummmmmm mase afarawe tori ohunti Taiye se
tomuje ,kehinde lese koyi lowo..
Beere lowo orire kotolo Pate nibi Oja gbe nta
Tori ohun gbogbo lowo ori ni ooo ooo….ire oooo
King Ogulutu Oro
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
Hummmmmm mase afarawe tori ohunti Taiye se
tomuje ,kehinde lese koyi lowo..
Beere lowo orire kotolo Pate nibi Oja gbe nta
Tori ohun gbogbo lowo ori ni ooo ooo….ire oooo
King Ogulutu Oro
Nje oda ki Ololufe Meji jo so bi won se gbe igbe aiye won kiwon to pade arawon paapa julo obinrin????
Omi pakiti o be ona lori,Ona na pakiti o be omi lori,ipade omi oun ona parapo won je merin adifafun oyigiyigi tin sota omi,awa doyigiyigi ao ku mon oyigiyigi ota omi……..
Ao ni ku ni rewerewe taye n yeni o,oju ejo kifo oju gbogbo wa koni fo o,ope ki kanju ku ao ni kanju ku o,ire gbogbo ni soju owo ire a ma soju wa oooo……
—-ELABORU ELABOYE—-
Prince Aberefa Adesola
Aaa eewo orisa iyawo-aare fe nan owo si alafin sugbon alafin ko(refuse) o kare baami iku babayeye gbogbo eni toba bami ri aisha buari iyawo aare orile-ede wa e bami sofun pe awa ki duro ki oba a ki bere ki oba beni aki bo oba l’owo(hand-shake) ayafi ti oba ba fe, idobale la ki oba. Aisha-buari e ma san iru aso be soro mo, e ma gbiyanju lati sope e fe ba iku baba-yeye bo-owo(hand-shake) agbedo ka ma ri, bi e ba nse be fun emir-kano, e ma dan iru re wo nile yoruba. ojulu emi o ni ki akalolo ma ke ewi sugbon koma k’ewi ki baba to bi mi l’omo. a bi kileni mowi gbogbo eyin ojulowo ooduarere te mo itumo asa (culture)?
Bio Bala alawipe loju orun olopa mue waa bo ninu ewu tio
koju dae sungbon ti olopa ba mue tio fi handcuff sie lowo
Oranla Kan nbo wa fune AFOWOFA arare ni yio si da oran
naa sie Lorun kio yara tete mura kio tera mo adua daada
pelu aawe bakan naa ti olopa bamu e ti won tie mole Cell,
Sora daada fun oore aseju kio Ma ko bae
Bio Bala alawipe loju orun oun gbale boya iwo nikan ni tabi
epo ala ikilo ni alayi Lasiko tio la alayi ogbodo Jina si ibinu
kio si Ma ba Eniyan ja nitori bio bajare iwo ni aye o pada da
lebi sungbon tio bale se suuru daada oore nla bowa fune
lati ibiti iwo Koro okan ire
Bi e ba lala wipe loju orun e’n sa ewa loju orun tabi e won
ewa loju orun oore ibukun lopo lopo lati odo olorun oba ni
ona owo lanla yio si Kano kio yara tete mura si adua ki
olorun oba ofi tete mu alare se
Ayandare Olasunkanmi Luqmon Ebedi > ALALILA PELU ITUMORE ATI ONA ABAYO LORIE whatssap or Calling 08089038658
Bi o bala ala wipe loju orun wipe e ri awon obo (monkey) meji loju orun tiwon tele ara won alayi dara pupo olorun oba yio seo loore male gbagbe orore yio dayo ona owo yio la fune beesini bio baje eniti onwa iyawo waari ololufe eni bi okanre gidi beesini bio baje obinrin tion woju olorun oba ni ibeji omo nwae bowa ni kiakia iwo olorun oba oore idunnu mi fi lemi lowo ooamin
Ayandare Olasunkanmi Luqmon Ebedi > ALALILA PELU ITUMORE ATI ONA ABAYO LORIE whatssap or Calling 08089038658
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Olori Aina Orosun ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata.
Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Oluwa e o ni ba won na oja warawara nile aye beeni e o si ni dagba yeye, gbogbo ohun rere ti n mu’le aye rorun fun eda ni Eledua yoo fi jinki yin. E o gbo, e o to, e o fewu pari, e o ferigi jobi, e o gbele aye sohun rere bi o ti wa wu ki e pe to laye e o ni f’oju mo saare omo lase Edumare.
Kabiyesi ati awon Oloye ati gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata nileloko nki yin wipe IGBA ODUN, ODUN KAN NI O.