Category: Àṣà Oòduà
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
-
Oju oge orekelewa iyawo K1 oba Fuji tasansan
Titi Masha ni yii, okan ninu awon orekelewa obirin ti K1 de Ultimate fi n segbaladun niyewu. Titi rewa pupo lobirin, oju re ri rekete bi ojo, ibadi aran ti n danilorun nigba gbogbo. [Olayemi, ara n fu mi si o]
Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin, Titi wa lara awon iyawo oba Fuji to wa lojuopon bayii, obirin naa si ni alase ati oludari Fathia Fabrics to wa ni Surulere eleyii to kale silu Eko Oba Akinolu.









-
E wo ohun ti Gomina Ambode ko fun awon agbofinro ilu Eko
-
Ojulowo-ogidi iya je awon ole ti won mu ni Mowe
-
Awon aye tun pade Fayose nile alapata
Gomina ipinle Ekiti, Ayodele Peter Fayose tun gbe ara mii yo pelu bo se gba obe alapata mu niso alapata eran to si bere si ni ge eran fun awon kositoma.
-
Dayo Amusa n dan bi egbin
Dayo Amusa rode ariya lonii ojo Satide. Omobirin naa si se afihan foto re ko to jade kuro nile. Ka ma paro, Alhaja yii fine gan-an.

-
Odun Thaipuisam: Irin sonso ni awon eniyan fi n gun ara won niluu India
Odun Thaipuisam je orisii odun kan ti awon elesin Hindu ti won gbe ni Guusu apa orileede ile India ma n se. Ninu odun yii ni awon eniyan ti maa fi irin sonso orisiirisii gun ara won ni gbogbo ara. Igbagbo won ni wi pe, bi inira won ba se po to nipa fifi irin sonson gun ibikibi lara won, bee naa ni ibukun won yoo se po to. Odun Thaipuisam ti di gbajugbaja ni ilu India, atokunrin atobirin ni won si n pejo nibi odun yii lati gba ibukun nla. -
E wa wo ohun ti omo Naijiria kan an se lori afara
Mo ri okunrin aro kan ti ko lapa kan lori afara ti awon elese n gba soda niluu Eko. Okunrin naa n fi igbale gba gbogbo ori afara laise wi pe enikeni gbese naa fun. Isesi okunrin naa wu mi lori, mo si sun moo lati foro wa lenu wo. ori re ko daru, eniyan tori re pe ni. Laipe, n maa salaye ohun ti mo mubo. Sugbon ohun kan lo damiloju, iye awon eniyan ti won ba Naijiria je le po, sugbon awon olododo eniyan kan si wa ti won tun un se pelu inu kan.

































