Category: Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

  • Aje olokun yo fiso sile gbogbo wa ooo

    AJÉ Iwọ́nrín Olókun a bi ara á ‘le koko bí ọta,
    Òhun l’ó d’ifa fún orí Àpéré ọ̀nà ọmọ a t’Àkàrà ṣ’ọlà..
    (Ajé brings prosperity. I wish all Ifa University members a prosperous Ifa year. )Aṣẹ.

    Adébóyè Adégbénró
    Photo Credit: Adébóyè Adégbénró

    aje_olokunaje_olokun1

  • Awure ki Ori gbe ni:

    Awure ki Ori gbe ni:
    Ori mi gbe mi re Ilu Ilaje
    Ibi kedere ni Ela gbemi lo
    Ori gbemi re Ilu Ilaya
    Ibi kedere ni Ela gbemi lo
    Sebi Iregbogbo lo n so ju Aje
    Iregbogbo ni se oju Olokun
    Ire tomi wa
    Ire tomi bo
    Oni ile ola
    Olo ono ola
    Ela Iwori je n ri Aje fii to omo mi Ela Iwori !!
    Except by engr Goriola,baba alawo Ile’lawa

  • Gbogbo oju to nwo aworan yi…

    Gbogbo oju to nwo aworan yi eni wole aisan won ni tayin lofa aburu ooo ao ni ri ogun ada njinan ooo !!
    oju

    Ase !

  • Grandson Blows Hot Again! Hotter Actually!!

    grandson

    Lets hear your thoughts in the comment box bellow.

  • Lobatan: Se pasto ni kape Eleyi ni abi satani (Satan) ninu bibeli ?

    defu
    Oni ki awon omo ijo Bora won si Ihoho ki oun tole gba adura fun ti awaon oponu omo ijo si bora won si Ihoho ni ita Gbangba, Ibere timo fe bere lowo awaon elesin cristeni ni pe se ara ire iranse na ni eleyi wa ni ?

  • Tani o Mo Oruko Kokoro Yi ?

    kokoro
    Edakun, tani mo Oruko ti won pe Kokoro yi ?

  • Moki gbogbowa wipe aku ewu osu titun ti o wọle de wẹrẹ waba waa !

    Mogbaladura wipe ogun aṣeti koni je tiwa ninu osu na,eni na tuni ọjọ (ẹtì) ti wonpeni (friday)…olodumare koni je ki akoju ogun aṣeti nile aye emi ati iwọ…
    ifa
    Ẹni tikole tele,ẹniti wa ọmọ latibi,ẹni fe aṣerori lori adawole ẹ,ẹni todawọ ikan tofe aṣeyori lori ẹ ki olodumare fun gbogbo won ni okun ati agbara lati ṣeyori..ase
    tori IFA kan so ninu odumimo ẹ bayi wipe….
    Abẹde awo olokira difa fun olokira eyiti otifi owun gbogbo se owoo aṣeti (woni o karanle ẹbọ nikose,owa rúbọ tan owa di alase yori)..nje abẹde o de oo awo olokira ORUNMILA jọwọ maki olokira o ṣe owo aṣeti…
    Njẹ́ abẹde o de oo awo olokira ORUNMILA jọwọ majeki awa ọmọ e kose owoo aṣeti…
    Ase…

    ~Ramon Nojim

  • Otito lawo aiye, iro lagbele ro !

    Owonrin omo ase’ka bi eni ti soo’to,
    yoruba

    Otito ba le di odo,
    ika bale di yangi,
    difa fun owonrin
    lojo tofe lo ya apo ika,
    E je kase otito,
    ka ya apo ika danu,
    Oore lope, ika koye omo Eniyan-
    – Ifa Owonrin-ika

    Truths is constantly exits ,only lies invented,
    Owonrin, the feigned honest man.
    Truth landed and changed to ocean,
    evil landed and changed to rock,
    divine for owonrin,
    … he was going to tear the pouch of evil into pieces.
    Let us tear the pouch of Evil and Wickedness,
    and uphold honesty and truthfulness,
    Kindness is a lucrative attitude
    Evil and wickedness has no profit for human .
    Extracted from – Owonrin Ika.

  • Oro kan se le si ore mi sugbon ko ye mi o!

    O gba obinrin kan si le sugbon obinrin yi gbe omo lowo sugbon bi ki ore mi ofe lo se obinrin yi le yin osun meji oro won ti wo de bi pe bi won ba ti ri ara won loju mon wala ni o le yin osun merin ni ja ba de lo ba pe baba omo hun ni ki oun wa lo fa ija o .e gbo se ki o gba abi ko fi si le o.
    oro_kan