FUNSHO ADEOLU tabi YOMI FASH LANSO

Category: Àṣà Oòduà
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
-
Moki gbogbo eyin Omo oodua pe asiku imura idibo tinbo yi
Eje kasora dada oledumare koni fi aburu kan wa .ki okunrin merin 4 ki oso eni ti afe ki owa lori aga agba loke loun .ki obirin merin 4 na funwa ni ti won .awon agba ni oun eyan loun oun olorun.eje kadibo larin arawa naa kamo eni ti yio wole .ki eniyan merin lokunrin .ati lobirin .kiwon so ero inuwon tagan na ni efe .ninu won. BUARI .JONATAR…
Ki ato wa dibo gomino .OYA KADIBO..TANI TIRE -
Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi !
ORIKI ORILE IREMOGUN:-Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.

Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni. Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ro baba.Omo bibi onire ni i remu sekele.Omo rowo-rowo-rowo.Balagbede o ba rowo.Toloko taladaa.Won a maa so lona oko.Ki lo mu ki won maa so lona oko?Ganiyu Soliu
-
Esu lalu okiri oko okiri ! (police of the universe)
-
Oro kan fun odaju abiyamo !
Eku ojumo esinku isimi oni,besini esin tun ku oro ilu, hmm awon yoruba ama paalowe wipe eniyo npanu eni ebinpanranku,Ewo omo tuntun jojolo yi nibi ti wonsonu si ninu poli bagi,sugbon osemilanu wipe omo natidagbere faye bayi ni oni paanu leko,awon kan nwa won ori beni awon kan ri wonmolo ,oro kan fun odaju abiyamo.

Benjamin Adekunle
-
Eledumare iba re loni o…
Eledumare iba re loni o,akoda aiye iba,aseda aiye iba,baba mi odetunde iba re loni o,iya mi iba re,iba oluwo ,iba iya nifa,iba olojo oni, aku ose ogun o,ogun yio bawa se o,ao ni tele lodi,ogun yio la ona fun wa o,Happy today’s ogun spiritual week. Ogun yee mo yee,iru ni aja fi n yin olowo re.





