Category: Àṣà Oòduà
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
-
Arakunrin yi se ijoba fun odun mefa !
N je o ye ki o tun so wipe o n tun fe se odun merin miran ati wipe se o ye ki yoruba se ati leyin fun









