Category: Àṣà Oòduà
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
-
Eji Ogbe Verse
Jọ̀gbọ̀dọ̀ lẹ̀fọ́ lorúko ti Ifá ńjẹ́
Ẹ̀rọ̀ wọ̀ loyèe tẹ̀tẹ̀Ayé kọpá
Ẹ̀sọ̀ lo gbàÈle tán láye
Ẹ̀rò ló kùA dífá fún Ìrókò Ẹlujù
Tí wọ́n ní ó máa so okùn
Kó tún máa so oyindẹÌrókò kó o má so èle
Ẹ̀rọ̀ were nÌrókò ń so
Ẹ̀rọ.Courtesy: Moyo Okedeji







