Home / Àṣà Oòduà / Ifá ní yini yini kí eni le se òmíràn

Ifá ní yini yini kí eni le se òmíràn


Adífáfún ifátérú tí se omokùnrin ìgódó,
Èdùmàrè àwa yìn ó kí o tún le se òmírán.?????
I give thanks to Elédùmarè, for everything he has done for me, orí modupe, Ifa modupe, Egbe aye ati t’òrun modupe lowo yin.??????

Thanks to everyone who wished me yesterday despite their tight schedule, thanks for the messages, calls, gifts, prayers, posts???? I am really grateful ?????May God bless you all?????I love you all❤️❤️❤️?

About ayangalu

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...