Category: Aworan
-
Eje ka dibo laarin awon olorin fuji mejeeji yi..
Laarin awon olorin fuji mejeeji yi.. TANI IWO FARAN JU LO?
-
Ona wo ni won maa ngba siku agbalagba ode?
Ni kete ti agba ode kan ba rewaleasa ni awon akegbe re ninu ode yoo mura lati wa sinpa fun un.Eyi ma n waye fun oku lati yo ese re kuro ni agboole ati laaarin awon olode yoku ti won jo nse ise ode.leyin eyi ni ijo orin pelu awejewemu yoo wa sese bere ni…
-
ORIKI ORILE IREMOGUN
Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni.Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ro baba.Omo bibi onire ni i remu sekele.Omo rowo-rowo-rowo.Balagbede o ba rowo.Toloko taladaa.Won a maa…
-
Eyin eniyan mi e ba mi dahun ibeere miyi:
Bawo ni awon yoruba se nki awon wonyi: (1)Agbede. (2) Ondiri (3) Babalawo (4)Akope Ati Alaboyun
-
Akuu dede asiko yii: Arakuriyii Lord lugard !
Arakuriyii ni. Lord lugard ohun loo so Nigeria papo. Ejowo se daada lose fun wa ni abi aida?