NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
16 November 2026
Àṣà Oòduà Aworan

ORIKI ORILE IREMOGUN

  • November 18, 2014
  • 1 min read
  • 4 Views
[addtoany]
ORIKI ORILE IREMOGUN

oriki
Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni.Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ro baba.Omo bibi onire ni i remu sekele.Omo rowo-rowo-rowo.Balagbede o ba rowo.Toloko taladaa.Won a maa so lona oko.Ki lo mu ki won maa so lona oko?Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi

About Author

oodua

Àtẹ̀jáde Tó Kọjá

Àtẹ̀jáde tó tẹ̀lé

1 Comment

  • A dúpẹ́ púpọ̀ fun oríkì orílẹ̀ Ìrèmògún yìí. Ṣùgbọn kò rọrùn púpọ̀ láti kà nítorí àìní ̀àmìn ohùn lókè àti nísàlẹ̀. Ẹ jọ̀wọ́ é bá wa se àtúnkọ rẹ̀.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *