Category: Aworan
-
Kini toko taya file gbe d’ojo ale
Kini toko taya file gbe d’ojo ale (1) Ife (2) Otito (3) Owo (4) Iro (5) Ibalopo
-
O pari!!!
-Ibanuje aye e pari loni -Ekun ose aye e pari loni -Ait’egbe aye e pari Lati eni lo -Iya e pari lati oni lo -Asedanu aye e pari lati oni lo -o tun r’arun owo mo lailai -O koni fosi logba -Owo,alaafia, ayo, omo, ise kekere owo nlanla ni ko maa ya s’odo e…
-
Ebami dasi oro yi !!!
Awon okunrin kan wa,nigba tiwon ba un nife Obinrin lowo,won ama se i love,i love u,titi ti obinrin na ma fi de ara si fun won.tiwon bawa ri wipe awon bani ajosepo tan,ti oyun de,won a ba yowo wipe awon ko ni awon ni oyun.titi osu mesan,won dasi obinrin na.won pati sepe kan,tititi omo na…
-
Iru ere wo gan loyan la yo nigba ewe re ?
Omo Oodua rere ajirebi? Iru ere wo gan loyan la yo nigba ewe re ? (1) Bojuboju (2) Bokoboko (3) Ekun meran (4) Suwe (5) Tete (6) Ere toko ti iyawo
-
Ejowo bawo ni ase le se oro yi ?
Lojo kan mo nlo si ilu keji legbe abule wa emi pelu agbebo adie merin ati agbado abo kan lojiji la de eti odo kan sugbon oloko oju omi ni nko ni anfani lati ko gbogbo awon eru mi lekan soso lodi keji odo kolokolo kan lo duro to nwo feto feto boya ebi npa…
-
Eyi ni aworan awon Omo ile iwe ti awon boko haram pa ni ipinle yobe
Eledumare bawa se iku ni isinmi fun won ki OSI ba Wa ro a won obi won lo ju ase awa naa oni fi Ojo olojo lo oooo