Home / Iroyin Pajawiri (page 106)

Iroyin Pajawiri

Se eyin tunle di ibo fun Arakunrin yi lekeji ?

Beni abi be ko?    

Read More »

Nje eyin ranti oruko oko ‪yi

kini oruko oko yi ?

Read More »

Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)

Arewa asa wa toni ni Alhaji Taiwo Hassan, abi won ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji ninu ile won,  Won losi ile-we alakobere ...

Read More »

Iwure Owuro Toni: 17-04-­2016

E MAA WI TELE MI : …… *Adun, ayo, idunnu ni temi titi aye *Ire owo, ire omo, ire aiku ni temi. *Apari inu mi ko ni ba tode mi je. *Orisun ayo mi ko ni gbe. *Ise mi ko ...

Read More »

Ojuitere !

ojuitere, iba re’oo baba IFAYEMI ELEBUBON, iba re’oo baba PETER IFATOMILOLA, iba re’oo baba, ADEBAYO IFALETI, baba wa AWODIRAN AGBOLA baba ADEGBOYEGA OMO ODO AGBA, awon agba onifa ti won gbo n’ti ifa n’so, sebi Yoruba bo won ni, KOSI ...

Read More »

Olobe Lo Loko Soko-Yokoto

Eto Olobe lo loko soko-yokoto ni o gori afefe bayii,,,,,, Adupe lowo olorun fun abo re lori wa, oba ti o pawa mo titi Di ojo oni, a dagbere ni ijejo, atun dupe wipe eledumare ka wa ye loni. Lori ...

Read More »

Ngozi Nwosu lori eto Gbajumo Osere

Read More »

What Ifa Says in Ogbe Ate

In Ogbe Ate, Ifa says everybody should do Itefa (Ifa initiation) to know one’s mission on earth, one’s destiny and in order to have all good things of life. A ki i ji ni kutukutu/ Ka ma modu to dani ...

Read More »

Eba Wa Da Si Oro Yii ooo

Eyin Okurin Se ele gba wipe ki Iyawo yin je oga yin ni ibi ise ?

Read More »

Arewa Asa Toni: Adekunle Kosoko (Gold)

Arewa asa toni ni olorin taka sufe (hip hop) ti gbogbo wa mosi ADEKUNLE GOLD, Won je omo bibi ilu Eko ni idile oba kosoko, ti wonsi jade nilewe gbogbo nise (polytechnic) towa nilu Eko enitoje awokose won nidise Orin ...

Read More »