Home / Iroyin Pajawiri (page 109)

Iroyin Pajawiri

Awon ojogbon fi oye dokita da Tinubu lola

Oloye agba egbe APC, Asiwaju Ahamed Bola Tinubu ni won ti foye dokita dalola bayii ni ogba Yunifasiti tiluu Abuja. Idalola agba oloselu to je gomina ti yoo je sikejila (12th) nipinle Eko lo waye ninu ayeye ikojade awon akekoo ...

Read More »

Rogbodiyan Mile 12: “Won ja omo ikoko gba lowo mi” – Abiyamo

Leyin rogbodiyan to be sile ni agbegbe Mile 12 to wa niluu Eko l’Ojobo ose to koja yii (03/03/16), okunrin kan ti oruko re n je Daniel Igba lo ti ke gbajari sita wi pe, awon kan ja omo gba ...

Read More »

E fun irun yi loruko ?

Read More »

Ipo wo ni iwo fe wa ninu awon olowo ile Afirika?

Ni owuro yii, mo fi akoko mi sile lati ka nipa aseyori Mike Adenuga, alase ati oludari ile ise ibanisoro Gbobacom. Ohun to ta mi kan ko ju iroyin tuntun nipa re eleyii to n se afihan re gege bi ...

Read More »

Omo odun metadinlogun (17) joba nile Naijiria

*Isele naa farape ti Awujale tile Ijebu Oba Sikiru Adetona, Awujale tile Ijebu, eni ti won bi lojo kewaa osu karun-un odun 1934 gori ite awon baba re lojo keji osu kerin odun 1960 leni odun merindinlogbon (26), eleyii ti ...

Read More »

Adewale Ayuba lori eto Gbajumo Osere

Read More »

Igbeyawo Ooni Ile-Ife fo yangayanga?

*Oba Ogunwusi n mura lati se igbeyawo tuntun   Lose to koja ni awon aheso oro kan be sile nigboro eleyii to ti bere si ni mu awuyewuye lowo bayii. Lara awon oro naa ni eyi ti n wi pe, ...

Read More »

Fayose setan lati ya awon osise lowo ra moto nipinle Ekit

“Ilaji owo osu won nijoba yoo ma yo fi san gbese naa” -Komisanna isuna owo Gomina Ayodele Fayose ti yanda owo to le ni igba milionu owo naira (N236,860,000) gege bi owo ti won ya soto lati ya awon osise ...

Read More »

Gomina ipinle Kwara ti da Jelili oniso lola

*Femi Adebayo n wonu oselu lo diedie Nibayii, gomina ipinle Kwara, Abdulfatah Ahmed, ti yan ogbontarigi onisetiata, Femi Adebayo, gege bi oluranlowo pataki nipa ise ona, asa ati irinajo-afe (Special Assistant on Arts, Culture and Tourism). Osere ti inagije re ...

Read More »

Kootu fi leta iku le Rev. King lowo

*Won ni ki won yegi fun un leyin to pa omo ijo re Reverend King Opin irin ajo ti de ba Rev. Chukwuemeka Ezeugo ti inagije re n je Reverend King nigba ti ile ejo to gaju yan-anyan, Supreme Court, ...

Read More »