Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won.

Iyabo Ojo dùn nínú aso tí kò bo ìdodo (crop top) tí ó wò.

Gomina Obiano lo kí Ààre Buhari ní Abuja léyìn tí ó gbégbà orókè níbi ètò ìdìbò tí won sèsè dì tán ní Anambra.

Arábìnrin yí ni ó jí èro ìbánisòrò ogbòn (30) tí ó sì ko pamó sí inú kómú àti pátá rè.

Nabila Fash kúnlè  Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ológun yí àti òdóbìnrin tí ó pàdé lórí èro ayélujára (Facebook) ya.

Flavour àti àwon omo rè obìnrin méjì, Sophia àti Gabrielle Okoli ti ya àwòrán tí ó ya ni lénu .

Àwòrán Yvonne Nelson àti Jamie Roberts, bàbá omo rè níbi tí won tí n fi ìfé hàn sí ara won.

Omobìnrin kan ní ilè Akwa Ibom ni àwon ebí rè ti fi sílè fún ikú sùgbón olùrànlówó kan ti gbà á kalé.

Arákùnrin kan ní Bayelsa ti se oúnje sí eran Anta tí ó pa.