Home / Iroyin Pajawiri (page 60)

Iroyin Pajawiri

Ayé k’áye ni eléyìí Ooo..

   Wón so ìran adúláwò dí eranko, kódà isé tí eranko kò le jé ni won n fi won jé . Won n lo ìran adúláwò n’ílò Ku lò.

Read More »

Kí olódùmarè sàánú ìran adúláwò.

     Kì í kú se wípé olórun d’àwa l’ájá béè kò dáwa l’éranko bí kò se wípé ó dáwa láláwò dúdú, ó sì dá àwon kan pupa. Sùgbón kò fi enìkan se erú enìkan.

Read More »

Juliet Ibrahim sí orékùnrin rè, Iceberg Slim, “mo dúpé wípé o gbà mí pèlú sùgbón mi.

    Juliet Ibrahim ti wà nínú agbami ìfé, nse ni ó dàbí pé ó ti pàdé adé orí rè. Òsèré kan ní orílè èdè Nàíjíríà ti fi èhónú rè hàn sí afòròdárà (rapper) kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Iceberg ...

Read More »

Igbo pàdé calabar, àwòrán kí won tó se ìgbéyàwó bí okùnrin náà se fi owó kó ìdí arábìnrin náà.

Àwòrán èyí kí ó tó di ojó ìgbéyàwó ti arákùnrin Igbo tí a mò sí Ofor, tí ó ti se tán láti fé aya àfésónà rè Witney tí ó jé Calabar ní ojó etì, ojó kejìdínlógún osù kokànlá odún yí ...

Read More »

Omoba Eze Madumere àti Chioma Rosemary kí omobìnrin kú àbò.

    Igbékejì Gómìnà ìpínlè Imo , Omoba Eze Madumere àti aya tí ó sèsè fé, Omoba Chioma Rosemary Madumere kí omobìnrin káàbò léyìn osù méjì léyìn ìgbéyàwó, won ti bí omobìnrin. Igbékejì Gómìnà ni ó pín àwòrán yí tí ...

Read More »

Peter Okoye àti Lola Omotayo se ayeye odú kerin ìgbéyàwó won.

   Olórin , Peter Okoye ti Psquare àti ìyàwó rè , Lola Okoye tí won ti wà papò fún bí odún métàlá se ayeye odún kerin ìgbéyàwó won.

Read More »

A ya àwòrán Bola Tinubu àti Osinbajo.

   Igbékejì Ààre Osinbajo àti baba ìsàlè egbé APC Bola Tinubu ya àwòrán papò lánàá níbi fífi ìwé l’ólè tí okàn lára àwon agbenuso ilé ìgbìmò so lórí bí Ààre Buhari se n gbógun ti ìwà jegúdújerá.

Read More »

Toke Makinwa ti ko àkosílè èróngbà rè fún odún 2018.

    Toke Makinwa ti ko èróngba rè fún odún 2018,tí ó sì ti setán láti gba odún náà towótosè . Lára àwon èróngbà rè ni Olórun, Ebí abbl.

Read More »

Patience Jonathan níbi ayeye ìgbéyàwó omobìnrin asojú ilé ìgbìmò asòfin, Sekibo.

     Aya Ààre télè, Dame Patience Jonathan yo ní àrà òtò láti yé adojú ilé ìgbìmò asòfin Thompson Sekibo bí ó se no àkóbí rè lówó níbi ìgbéyàwó yí ní ìlú Ogun.

Read More »

A ya àwòrán Bola Tinubu àti Osinbajo.

   Igbékejì Ààre Osinbajo àti baba ìsàlè egbé APC Bola Tinubu ya àwòrán papò lánàá níbi fífi ìwé l’ólè tí okàn lára àwon agbenuso ilé ìgbìmò so lórí bí Ààre Buhari se n gbógun ti ìwà jegúdújerá.

Read More »