Home / Iroyin Pajawiri (page 69)

Iroyin Pajawiri

Àwòrán tí Aduni Ade àti omo rè okùnrin yá tí ó sì wuni .

    Arewà tí ó bí omokùnrin méji ni ó pín àwòrán òhun àti ìkan lára omo rè méjì sí orí èro ayélujára (Instagram). “Won n bínú wíwà l’áyé wa Tí ó sì jé wípé àwon ni won sún mó ...

Read More »

Kàyééfì ò ní yé selè, odóbìnrin kan ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti lógò starboy sí èyìn rè.

    Òkan lára àwon olólùfé Wizkid ni ó ya tàtúù ojú Wizkid àti logo starboy sí èyìn rè…

Read More »

Asojú ilé-ìgbìmò asòfin Ademola Adeleke, ni a rí tí ó n jó pèlú àwon arewà.

Àwòrán ègbón Davido, asojú ilé-ìgbìmò asòfin ní bi tí ó ti n jó láàrin àwon arewà…

Read More »

Opolo arakúnrin yí yanilénu.

Arákùnrin ará Cameroon ni ó fi igi oparun gbé kúlà yí, eléyìí tún ya ni lénu ooo…ogbón kìí pé ní ilé ayé sha…

Read More »

Eléyìí tún ya ni lénu ooo! Àwòrán akékòó tí ó pa ara rè.

     Ní àárò ojóbò, ojó kerìndílógún osù kèwá, (26/10/2017) ilé-ìwé Obafemi Awolowo University (OAU) àti agbègbè rè pàdánù omo ilé-ìwé kan tí ó n jé Afolarinmi Mercy tí ó wà ní ìpele àkókó (100level) ní eka èkó Micro biology…

Read More »

Selena leath pín àwòrán sáàjú àti léyìn òun àti Runtown àti omokùnrin won.

Ìyá omo Runtown, Selena leath pín sí orí èro ayélujára àwòrán sáájú àti léyìn òun àti Runtown pèlú omokùnrin won, Zamar…

Read More »

Nínú agbami ifè ni won wà, gbajúmò òsèré Mode Funmi Martins àti oko rè Afeez Owo fi ìfé won hàn.

À béè rí nkan, e ri bí won se se jómúrégí papò! Won bá ara won mu gan ni…

Read More »

Àwòrán tí ó ti pé ti gbajúgbajà òsèré Odunlade Adekola.

     Àwòrán ìgbà èwe ni ní tòótó fún gbajúgbajà òsèré Odunlade Adekola. Táà bá ní pa iró owó dáa l’ára…

Read More »

Òdóbìnrin orílè-èdè Nàíjíríà kan se ayeye ojó ìbí rè tí ó sì há oúnje fún àwon aláìní.

    Òdómobìnrin orílè-èdè Nàíjíríà ni ó pinnu láti se ayeye ojó ìbí ní àrà òtò, nígbà tí a ri tí ó n pín oúnje àti àwon nkan míràn fún àwon aláìní, omodé àti àwon èèyàn míràn . ònà ni ...

Read More »

Oba Orin Sunny Ade àti Flavour Jo hàn ní orí ìtàgé.

     Oba orin Sunny Ade àti Flavour dìjo dá àwon ènìyàn l’ára yá lórí ìtàgé. Pèlú èrín ojú Flavour n se ni ó dà bí eni wípé inú rè dùn láti pàdé oba orin…

Read More »