Category: Metro life
-
Iriri awon omuti: Ore meji ku, iketa fara pa
Gege bi oro awon Yooba,”eni Sango ba toju re wole, eni naa ko ni ba won bu oba Koso laelae.” Okunrin kan to pe ara re ni Cde Zenzele Nkosi lori FACEBOOK lo salaye ijamba moto to sele si i nipa iwa oti mimu pelu oko wiwa. Okunrin naa se afihan foto oju-apa to gbe…
-
Omo Gomina Ambode n je igbaladun Sande lowo
Kosi ise lonii ojo Sande l’Alausa. Ile ni Habib Aruna, akowe iroyin fun gomina Akinwunmi Ambode, wa pelu aya re. Awon mejeeji jo n je igbaladun ara won loni miliki.Ki lo tile kan mi na lori oro oko ati iyawo oniyawo? Eniwee, mo laiki tattoo to wa lapa ati owo madamu o. Tattoo naa fine…
-
E wa wo ohun ti omo Naijiria kan an se lori afara
Mo ri okunrin aro kan ti ko lapa kan lori afara ti awon elese n gba soda niluu Eko. Okunrin naa n fi igbale gba gbogbo ori afara laise wi pe enikeni gbese naa fun. Isesi okunrin naa wu mi lori, mo si sun moo lati foro wa lenu wo. ori re ko daru, eniyan…
-
Se Gbenga Adeboye lo ko Wale Dada nise sorosoro?
Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lori eto naa ni won ti beere lowo enikan to ti fi igba kan dije gege bi omo ile igbimo asofin ipinle Ogun boya leyin Gbenga Adeboye Abefe lo ti…
-
Yemi Osinbajo: Ori taa fi sewe
Igbakeji Aare, Yemi Osinbajo nigba to wa nile iwe alakobere Corona School, Lagos. Awon Yoruba bo, won ni ori taa fi sewe kii kuro lorun eni taa ba dagbalagba.
-
E wa wo ohun ti oludije ipo gomina n se lagbala pelu aya re.
Eng Seyi Makinde, okan ninu awon oludije ipo gomina nipinle Oyo, labe egbe oselu SDP ninu eto idibo odun 2015 to waye ni yii pelu aya re. Gege bi iwadii Olayemi Oniroyin lati enu awon to sun mo eni ti awon kan tun mo si Omi Tuntun. Won fi ye Olayemi Oniroyin wi pe, maanu…
-
Kini yoo sele si orekelewa aya Abubarka Audu?
Omodebirin yii ni okan ninu awon iyawo tuntun ti Abubarka Audu ko sile to fi n sararindin nigba aye re. Gege bi ohun ti Olayemi Oniroyin gbo, ojo ori omobirin naa ko le ju bi odun mejidinlogun (18) si ogun odun (20) lo. Nibayii ti baba olowo eni odun mejidinlaadorin (68) ti wa ku lairo…
-
Maheeda di Pasito oloro itunnu
Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n mu inu awon ololufe re dun.
-
Dapo Lam Adesina n fo lo si ilu Jamani
Omo gomina ipinle Oyo nigba kan ri, to tun je okan lara awon omo ile igbimo asoju-sofin ilu Abuja, Dapo Lam Adesina ti n gbera lo si ilu Jamani bayii lati lo yanju awon akanse ise ilu ti won gbe le e lowo. Onarebu Dapo je okan lara awon oloselu ti won maa teti si…