Home / Esin (page 2)

Esin

Video: Bàtá Dancers Appeasing Ṣàngó

The Bata Dancer is famous in the western region of Nigeria, home of the Yoruba Tribe. Associated with Sango – God of Thunder – the Bata Dancer moves to the beat of the Bata drum.Traditional Bata Dancers worshiped Sango, and ...

Read More »

Ifa physiology: Ojú/Eyes

Ojú. Ojú lalákàn fi í sọ́rí. Ojú oró ní í lékè omi. Ojú ò ní tì wá lótù Ifẹ yìí láíláí. Ojú ò níí relé de ìkankan nínú àwa ọmọ Awo. Eyes–Oju With the eyes, the crab watches the ori. ...

Read More »

Ifalodolu korowísí korowísí èmi…

Ifalodolu korowísí korowísí èmi na lodolu korowìsìkorowìsì baba mi agbonmniregun baba mi elesin-oyan mo ni ao ri wu oba ba won yiri oba tojoba tan lalede orun odele aye tan oda osere oun egbe le oloun opa iru omo eku ...

Read More »

Esu lalu okiri oko okiri ! (police of the universe)

Esu lalu okiri oko okiri ogo(police of the universe) ako ebo ti ofi orita se afin.Laroye ebora ti ron oju mo omo kinkankinkan. Esu mase mi omo elomi ni kose……….n.

Read More »

Eledumare iba re loni o…

Eledumare iba re loni o,akoda aiye iba,aseda aiye iba,baba mi odetunde iba re loni o,iya mi iba re,iba oluwo ,iba iya nifa,iba olojo oni, aku ose ogun o,ogun yio bawa se o,ao ni tele lodi,ogun yio la ona fun wa ...

Read More »

IWURE ODUN TUNTUN 2015

IWURE ODUN TUNTUN A si ku odun, a ku iyedun. Olodun a wo omo fun wa. Kewekewe koni ko wa l’omo lo. Aseye ni alakan ns’epo ti e Aseye ni tiwa o. Aseti, akoti koni kan wa T’oko, t’aya ati ...

Read More »