NEW! Àǹfààní àgbàyanu fún àwọn ọmọ ẹgbẹ́ pàtàkì wa!Ka siwaju
38°C
21 November 2026
Àṣà Oòduà Iroyin Pajawiri

Iwure Owuro Ipari Osu

  • April 30, 2016
  • 1 min read
  • 6 Views
Iwure Owuro Ipari Osu

E MAA WI TELE MI :
…..
*Airije-airimu nile aye mi ti dopin.
*Ibanuje ninu aye mi ti dopin.
*Ijakule ninu aye mi ti dopin.
*Ise mi ko ni dojuru
*Ogun aye ko ni borii mi.
*Oju owo ko ni pon mi.
*Imole mi ko ni di okunkun.
……………
‪#‎OLUWURE‬ : Isese omo Oodua Foundation ‪#‎IOF‬.

About Author

ayangalu

Àtẹ̀jáde tó tẹ̀lé

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *