Home / Tag Archives: Iwure

Tag Archives: Iwure

Iwure AJE

Iwure AJE Toni. Aje wa fii ile mii se ibugbe ❗❗❗ Aje iwo lobi Ogun ilu Aje iwo lobi Olufa Aje iwo lobi onipasan owere Oyale asin win bear asin win dolowo Oyale asi were oso asi were di aniyan-pataki Aje ...

Read More »

Iwure Ojo Eti

Moki gbogbo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla wayi o Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (.Ilosiwaju Ishese Lo Jemi Lo Gun o.) Mofi asikoyi gba ni iwure fun gbogbo eda omo adariwuhun tioba lefi atejishe ee se (Aseee) labee ...

Read More »

A o ni jin sofin aye pelu ase Olodumare. Ase o…

Ofun saa lefun Ofun saa losun Ofun saa ni moriwo Ope yeyeye A difa fun Alagemo terekange Tii se Omo Orisa igbowuji Nitori ajeku Baba Alagemo Nitori amunku Baba Alagemo Won ni ki Alagemo losi apookun Kio lo si ilameji ...

Read More »

Iwure Osu Tuntun 01.07.2016

E MAA WI TELE MI : ………… *Osu yii, osu aseyori mi ni. *Osu iserere mi ni lase Edumare. *Osu igbega mi ni. *Osu idunnu mi ni. *Owo a fi ilee mi se ibugbe. *Akoba, adaba ko ni je temi. ...

Read More »

Iwure Owuro – 05.07.2016

E MAA WI TELE MI : …….. *Edumare ma se je ki n fi ota s’ore. *Oluwa gba mi lowo afoju-feni ma fokan-feni. *Edumare gbe mi leke abinu eni. *Oluwa ma se je ki n je egungun kehin eran. *Edumare ...

Read More »

Iwure Owuro Toni 04-05-2016

E MAA WI TELE MI : ……… *Owo ko ni ri mi sa. *Oju owo ko ni pon mi. *Ojo ibukun mi ko ni di ojo abuku. *Alaaanu mi ko ni ko’yin si mi. *Edumare ma je ki n teni ...

Read More »

Iwure Osu Tuntun 01-05-2016

E MAA WI TELE MI : ……… *Osu karun-un yii, osu ire owo ni fun mi. *Osu ire ile kiko ni fun mi. *Osu ti maa ra oko ayokele. *Osu igbega lenu ise mi ni. *Osu idunnu ni yoo je ...

Read More »

Iwure Owuro Ipari Osu

E MAA WI TELE MI : ….. *Airije-airimu nile aye mi ti dopin. *Ibanuje ninu aye mi ti dopin. *Ijakule ninu aye mi ti dopin. *Ise mi ko ni dojuru *Ogun aye ko ni borii mi. *Oju owo ko ni ...

Read More »

Iwure Owuro Toni: 24-04-2016

E MAA WI TELE MI : …… *Ade ogo mi ko ni si danu. *Aso iyi, aso eye mi ko fa ya. *Edumare ma je ki n fi ota se ore. *Oluwa dakun so egan mi dogo. *Edumare wa so ...

Read More »

Iwure Owuro – 09/04/2016

E MAA WI TELE MI : ………. *Edumare pase irorun sinu aye mi. *Oluwa tanmole si ogo aye mi. *Eni to n se atako ire aye mi, Oluwa f’eje re setutu ola mi. *Oluwa gbe alaanu dide si mi. *Pasan ...

Read More »