Home / Àṣà Oòduà / Olopa pa obirin kan ni ilu Eko

Olopa pa obirin kan ni ilu Eko

Olopa yinbon pa iyawo ile kan , ni adugbo kan ti aun pe ni Onipanu ni ilu Eko, nigba ti oun le ikan ninu awon
omo ti won ma un fi ero ayelujara jale. Awon agbofinro so wipe won yi o se iwadi isele na.
Eyin ni awo ran obirin na.

 

English Version

Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo