Home / Àṣà Oòduà / Gbajúgbajà Olórin, Diamond Platnumz Ti Yanjú Aáwò Tí Ó Wà Láàrin Òhun Àti Ìyá Omo Rè

Gbajúgbajà Olórin, Diamond Platnumz Ti Yanjú Aáwò Tí Ó Wà Láàrin Òhun Àti Ìyá Omo Rè

Gbajúgbajà olórin ní ìlà oorùn adúláwò tí a mò si Diamond platnumz ti yanjú aáwò tí ó wà láàrin òhun àti ìyá omo rè léyìn wákàtí tí ó bá a wí fún àìso òtító . Ó pín eré oníse amóhùn máwòrán (video) tí òhun àti omo àti ìyá omo rè hàn nínú è “mo ti sòrò ” won jùmò pa ohun tí won fi sí orí aféfé ré. Ó tún pín eré obese amóhùn máwòrán òhun àti Zari pèlú àwon omo won tí won ń seré pèlú ohun tí a mò sí “yà  ko  tè “(snapchat)…….

English Version

Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?