Home / Àṣà Oòduà / Odomokunrin Kan Ni Orile Ede Naijiria Ati Ara Binrin Oyinbo To Sanra Mu Ki Awon Eniyan Soro

Odomokunrin Kan Ni Orile Ede Naijiria Ati Ara Binrin Oyinbo To Sanra Mu Ki Awon Eniyan Soro

Oro to panilerin ninu itakuroso ti o wa laarin arakunrin yi ati ololufe re tele eyi ti o yan je. Arakunrin naa kunle lati beere owo owo arabinrin orobo yi fun igbeyawo..

Eyi ni lati fi ife otito han si ololufe re, odomokunrin ile naijiria ti di gbajugbaja lori ero ayelujara. Arakunrin yi fi aworan ohun ati ololufe re han nigba ti won n sere ife lowo. Eyi je iyalenu fun opo eniyan.


English Version

Continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo