Home / Àṣà Oòduà / Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !

Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !

Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun re orewa? Ara-ile mi ko se eni eniyan mi kose eniyan ao ma gbodo fi we alaro (companion) lasan, e seri wa ‘le kie wa tun ile baba yin se. toripe bi omo ba-ko(refuse) ti ile ile yo le omo lo si ajo(journey) sugbon toba ya toba pe ajo yo le omo pada wa si ile, lafi ni kema gbagbe ipile, orewa ma ti toripe oun lo si ede(ede-town) ko wa ba ede(home) je, toripe eniyan toni pe arajoun kose rere iyalaya ati babanla re lo ba wi.
Oju-itere ojulowo omoyorubaatata

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo