Home / Àṣà Oòduà / Fi ere si temi Eledumare

Fi ere si temi Eledumare

Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan
bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko
taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN
KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe o bami
se amin O NI KAABAMO LORI IGBESE RE. oju-
itere ojulowo omoYORUB Aatata

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo