Home / Àṣà Oòduà / Orewa kilode kilo fa ironu?

Orewa kilode kilo fa ironu?

Bao ku ise o tan toripe yoruba bo won ni airise koni kapada si orun-alakeji tiko basi oko (farm) ao si ma re idale(travel) ko si eni to la laye yi tiko ni ri nkan wi, amo saa ti oro bari bayi, eledua lo ye ka ke pe pelu igbiyanju toripe die omokunrin ki to sugbon ju gbogbo re lo iwon tun won si nile aye, sugbon sa tia ba ri eni tofe ma tie giragira to fe kosa ere koja kadara re, sofun won wipe orisa-oko ko sowipe oun ko ba isu-egbodo se sugbon asiko ti orisa yo je isu ni koi ti to.

Oju-itere ojulowo omoyorubaatata

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?