A dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ Baálẹ̀ Yemọja, Ìyá Omítọ̀nàdé, Ẹbí, Ará, gbogbo Àgbà àti Ọmọdé… Ìbà Olódùmarè, ọdún pé, ọdún jọ. .To all friends, fans and well wishers, we’re grateful.
Read More »Àwọn Yèyélórìṣà, Akirè Shrine Ilé Ifẹ̀, 2003.
Pitcture was taken by Prof. Moyo Okediji in 2003, he returned to find the group in 2015. But for the two women at the extreme left, all the others had transitioned.
Read More »Transforming Ìṣẹ̀ṣe Temples, Shrines, Houses Of Worship
Women devotees live in a sanctuary that attends to both their spiritual and physical needs at the Àkòdì Òrìṣà. We train them to produce things that can be marketed. Spirituality is great and necessary. But we also have material needs—which ...
Read More »Èmi kò fé̩ràn láti máa fe̩nu ko obìnrin lé̩nu nínú eré – Taiwo Hassan
Taiwo Hassan Ọlọ́jọ́ọ̀bí, akọni òṣèré Yollywood tó dáńtọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Yoòbá bọ̀, wọ́n ní èèyàn tó bá monú-ún rò, ọpẹ́ ẹ rẹ̀ yóó lékún bóyá n ló fa sábàbí bí ọ̀gọ̀ọ̀rọ̀ ọmọ Nàìjíríà ti ń darapọ̀ kí àgbà òṣèré Taiwo ...
Read More »Ori mi Apeere
Ka ji ni kutukutuKa mu ohun ipin ko’pind’Ifa fun Olomo-ajiba’re-padeEmi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pinEmi ni mo ba ire pade nigba gbogbo ori mi apeereAteteniranAtetegbeni ju OrishaKo si Orisha ti danni gbe leyin ori eniOri ...
Read More »Orisa Alaase, Igbakeji Olodumare
Happy Oosala day to people across the globe.
May we have the blessings and goodness of it. Ase Edumare! Olokun asoro dayo, olokun ajeti aye, olokun iserin ade. All these are names of Orunmila. Now the question is. Is Orunmila same as Olokun? Is Olokun not an orisa ...
Read More »