Home / Àṣà Oòduà / Aye akamara: Abiyamo gbe omo re ta nitori owo

Aye akamara: Abiyamo gbe omo re ta nitori owo

Owo awon osise alaabo ti won dabo bo dukia ijoba, Nigerian Security and Civil Defense Corps, NSCDC, e ka ti ipinle Enugun ti te arabirin kan to fe ta omo bibi inu re ni egberun lona ogorun owo naira Naijiria.

Arabirin Nkechi Isioko to n gbe ni Mpu to wa ni ijoba ibile Aninri nipinle naa ni owo awon osise alaabo NSCDC te nibi to ti n gbiyanju lati ta omo re fun arabirin kan ti oruko re n je Blessing Egbo.

Gege bi oro Nkechi, o ni won ti pada gba oun ni imoran lati ma ta omo naa mo. Oun si ti setan lati da owo naa pada fun Blessing. Nkechi ni iponju ati osi lo sun oun debi iwa palapala bee.

Titi di akoko yii, enikeni ko mo ohun pato ti Blessing fe fi omo to ra se.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo