It is a well thought point that deserves commendation. Oduduwa begat Okanbi. Oduduwa is the first Ooni. Ooni is the shortend version of the appelation of Arole Oduduwa. Oonile is the owner of the land. He is also Oonirisa. He is number 201st of irunmoles in Yoruba land. Kabiyesi Oonirisa, the father of all Yorubas all over the universe.
Author: Lolade
-
Foto Mercy Aigbe meje (7) to ta lenu bi ataare
-
Awada Kerikeri: Awon ole meji ti won lo fo banki
Awon ole meji ja ilekun banki kan loru ojo kan, won si n si awon seefu wo. Ninu akoko, yugooti bi i meloo kan ni won ri nibo, kò s’ówó. Won to yugooti naa wo, o ti kan lenu.Won sikeji wo. Yugooti ni won tun ri nibe, won tun wo, won si ri wi pe, iyen daa lenu die. Sugbon ko tun s’owo nibe.
Won tun siketa, yugooti naa lo wa nibe.
Okan ninu won koju sikeji re, o ni “John, ki lo de to o lo sita. Ko o lo woo boya banki la fo looto, ki o si jokoo lati gbadun yugooti eyi to dun yi.
Leyin iseju die John pada de. O ni “A o kuku sile ya, banki la wa!”
Ekeji re ni “Ki gan-an ni won ko sara patako akole re?”“Sperm Bank ilu New York!”Akoba gaaaafara!!!http://www.olayemioniroyin.com/2015/10/awada-kerikeri-awon-ole-meji-ti-won-lo.html -
Photos: Meet the New Ooni Of Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Kabiyesi O)
ki Ade ko pe lori ki Bata pe lese o,Kabiyesi o..
Adeyeye Enitan Ogunwusi from the Geisi ruling house has been unveiled as the new Ooni of Ife. Moshood Adeoti, secretary to the Osun state government, confirmed this in an announcement.
“The governor of the state of Osun, Ogbeni Rauf Adesoji Aregbesola, has approved the appointment of a new Ooni of Ife,” the statement read. “He is Prince Adeyeye Enitan Ogunwusi of Geisi ruling house of Ile-Ife, state of Osun. This choice follows the completion of the due process by the kingmakers and the communication of their decision to government.”
The new monarch succeeds Okunade Sijuwade, who died in July after presiding over the kingdom for 35 years. Sijuwade hailed from the Ogoru ruling house and had a tremendous reign. A graduate of accountancy from The Polytechnic, Ibadan, Ogunwusi is the 51st monarch to sit on the prestigious throne.
The 40-year-old is into real estate and has several properties in Lagos. Ogunwusi is a director on the board of directors of Imperial Homes Mortgage Bank Limited, a leading mortgage bank and former subsidiary of GTBank Plc. He is also a director, FinaTrust Microfinance Bank Limited, one of Nigeria’s foremost microfinance banks focusing on SMEs and micro credit facilities. He is the founder and managing director of Gran Imperio Group, the holding company of real estate and construction, manufacturing, facilities management, leisure and tourism companies in Nigeria.
-
Buruji Kashamu je gbese! Ile ejo ti fagile eto idibo to gbe wole gege bi senator
Ile ejo ti fagile eto idibo to gbe Senator Buruji Kashamu wole sile igbimo asofin agba Abuja lati soju Ogun. Won ni magomago po ninu eto idibo naa, ati wi pe won yoo tun ibo naa di ni.
-
Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin ti

Ebora ilu Owu di Ebora agbaye: Won Fi Obasanjo je siamaanu awon aare orileede agbaye to ti feyin tiAare ile Naijiria nigba kan ri, Olusegun Aremu Obasanjo baba Iyabo ni won ti yan bayii gege bi siamaanu igbimo egbe awon aare ti won ti feyinti agbaye, World Council of Ex- Presidents.
Itesiwaju tuntun to de ba Ebora ti ilu Owu yii ni a le gba wi pe o n jeri alaye re nigba kan, nibi to ti n se alaye ara re gege bi asaaju ile Naijiria, ile adulawo ati agbaye lapapo.
Obasanjo ti o ti fi igba kan je alaga egbe African Union ni won ti yan gege bi alaga eleekarun-un bayii fun igbimo egbe awon aare agbaye to ti feyin ti. Awon ti won de ipo naa saaju ni:
(1) Helmut Schmidt lati Germany
(2) Malcolm Fraser lati Australia
(3) Jean Chretien lati Canada ati
(4) Franz Vranitzky lati AustraliaOrisun: http://www.olayemioniroyin.com/
-
Iwe Iroyin Owuro ose yii kun fofo bi ataare

Ti eyin ko ba tii ra iwe Iroyin Owuro to jade lose yii, a je wi pe iroyin ku sibi kan te e ti gbo.Lati ori oro oselu de amuludun, awon oro to n lo ati igbelaruge asa ati ise Yoruba; gbogbo re lo kun fofo bi ataare.
Die ni yii lara awon koko iroyin to jade:
*Orangun yari mo Aregbe ati Owa Obokun lowo
*Alison-Madueke ko si panpe Buhari niluu London
*”Ijoba ibile wa kii fun Tinubu ni owo kankan”- Alaga kansu lo so bee
*Odun Ominira: Okan awon omo Naijiria tun taji si orileede won.
*”Obe didun ati ere ori beedi ni mo maa fi n mu oko mi mole” – Ronke Osodi-Oke
E ra iwe Iroyin Owuro ti ose yii lati ka awon ojulowo iroyin yii ati awon mii. Ogorun-un naira pere ni. Aye gbogbo wa yoo toro bi omi a fowuro pon o. Amin #IroyinOwuro deeeee!
-
Ahmed (Amedi) Musa lo rawon julo bayii niluu Russia

Ogbontarigi agbaboolu omo Naijiria, Ahmed Musa, ti n le waju bayii ninu awon agbaboolu to rawon julo niluu Russia. Iroyin yii jade ni kete ti egbe agbaboolu re, CSKA Moscow jawe olubori nigba ti won pade pelu Dynamo pelu ayo meji sodo. Musa naa gba goolu kan wole ninu ifesewonse to waye lopin ose yii eleyii to mu apapo boolu to gba wole je mefa ninu liigi oreede Russia.







