Aare ilu South Africa, Jocob Zuma, ti fi owo si abadofin lati maa sami si egbe kan oju ara awon ti won ba ni kokoro HIV lara. Won ni nipa sise eleyii, yoo mu adinku ba awon eniyan ti won ...
Read More »Iresi Gomina Ayodele Fayose Tun Pada Wo Ipinle Ekiti
Ikere Ektiti ni won ti pin. Atomode atagba, arugbo naa gba ninu iresi Fayose. Ohun ti awon eniyan so nipa re wa nibi:
Read More »Oko Ajagbe Eleru Leyin Jabo Lati Ori Afara Ojuelegba: Emi Awon Eniyan Ba Lo
Oko ajagbe eleru leyin kan jabo lati ori afara to wa ni Ojuelegba niluu Eko losan-an oni. Eniyan meji to wa ninu oko ti ajagbe naa jabo le lori fi ile aye sile loju-ese ti isele naa waye nigba ti ...
Read More »Oriki Ibeji : Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún
Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. Ẹdúnjobí Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ. Wínrinwínrin lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ...
Read More »Odaju Abiyamo Fi Ina Jo Omobirin Eni Odun Merindinlogun Loju Ara: O Ni Omo Naa N Se Agbere
Omobirin odaran kan ni owo awon olopaa ti te ni agbegbe Ketu niluu Eko pelu bo se fi ero ayoonu iloso jo omo egbon re ti n gbe pelu re, Bimpe Badmus, omo odun merindinlogun, nidi pelu esun wi pe ...
Read More »Awon Foto Lati Ibi Ijamba Oko Ofurufu Awon Omo Ologun Niluu Kaduna
Awon aworan Oko ofurufu Dornier 228 ti awon omo ologun ile Nigeria ti a kede wi pe o jabo loju orun laaro oni ni yii. Awon eniyan meje ti won wa ninu oko ofurufu naa lo parun patapata.
Read More »Aso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri: Jenifa Pe Omo odun Mejidinlogoji (38)
Aworan Funke Akindele niyii niluu Oba nibi to ti n yo ayo ojo ibi re to ko laipe yii (August 24). Ka ma paro, Funke Akindele ta lenu! Lati irun ori re de bata to wo sese ni i sana ...
Read More »Oko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna
Oko ofurufu helicopter eleyii ti awon ologun n lo fun idanileko lo jabo ni ibuba awon omo ologun to wa ni Kaduna leyin iseju mewaa to gbera soke. Ilu Abuja lagbo wi pe oko ofurufu naa n lo ki lala ...
Read More »Radio Biafra Ti Pada Senu Ise: Se Kii Se Wi Pe Awon Omo Yibo Fe Da Ogun Biafra Mi-in Sile?
Ile ise Radio Biafra ti ikanni re je 104.7 FM eleyii ti won bere si gbe ohun safefe lai gbase, ti ijoba si ti siwon lowo ise ninu osu keje tun ti pada gbe ara otun mi-in wo bayii. Ko ...
Read More »Mercy Aigbe Ra Langbe Je Lorita
Irawo oserebirin, Mercy Aigbe aya Lanre Gentry, ni won ka mo odo iya alagbado nibi ti omobirin naa ti n ra langbe je. Oserebirin to kawe gbogbo ninu Ere Onise ti a mo si Theatre Art ni Ifafiti ijoba apapo ...
Read More »