Home / Àṣà Oòduà / Mercy Aigbe Ra Langbe Je Lorita

Mercy Aigbe Ra Langbe Je Lorita

Irawo oserebirin, Mercy Aigbe aya Lanre Gentry, ni won ka mo odo iya alagbado nibi ti omobirin naa ti n ra langbe je.  Oserebirin to kawe gbogbo ninu Ere Onise ti a mo si Theatre Art ni Ifafiti ijoba apapo to wa niluu Eko lagbo wi pe o bere ise fiimu agbelewo lodun 2006.  Omo bibi ilu Edo ni sugbon ede Yoruba eni re da saka.

About Lolade

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?