Home / Author Archives: oodua (page 9)

Author Archives: oodua

Aye awon asewo nile awon omo yahoo-yahoo

Bi yahoo-yahoo ni won ni abi ogun oloro ni won gbe, ta lo mo. Sugbon o daju wi pe, eni to n sise gege bi omoluabi ko ni da iru eleyii lasa wo laelae. Ori ayelujara ni aworan yii ti bere ...

Read More »

Obirin kan bi omo sinu Keke Maruwa

Onise ara ni Olorun oba. Omobirin alaboyun kan lo bere si ni robi ninu Keke Maruwa ni akoko ti won gbe lo si ile iwosan lati lo bimo niluu Enugun.  Eyi to ju ibe ni wi pe, ojo odun lo ...

Read More »

Won ti fi Ladoja je Osi Olubadan

Won ti fi Senator Rashidi Adewolu Ladoja je Osi Olubadan lonii (01/01/16) ni aafin Oba Samuel Odulana Odugade, Olubadan tile Ibadan.

Read More »

Amosun se ileri ipe ofe ori foonu fun awon osise lodun 2016

Ijoba ipinle Ogun, labe akoso Senator Ibikunle Amosun, ti se ileri ipe ori foonu ofe fun gbogbo awon osise ipinle naa lodun tuntun 2016 to wole de yii.  Igbese tuntun yii ni olori eka imo ero ati ibanisoro, Ogbeni Olatundun ...

Read More »

Davido ti toro aforijin lowo Dele Momodu

Davido ti toro aforijin lowo Dele Momodu fun awon oro alufansa to so si i lori wahala to wa laaarin re ati afesona re igba kan, Sophie Momodu to je aburo Dele Momodu,

Read More »

E pade awon ore yin nibi

Orisiirisii ona ati idi pataki ni awon eniyan fi n yan ore tuntun. Awon kan fe alajoso, awon kan fe alabaro, awon kan si n fe eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Eyiowu ko je, ore dun ti ...

Read More »

Won ti se idajo Sharia fun alagbere obirin

Obirin yii ni won ti se idajo Sharia fun ni orileede Indonesia latari wi pe, gbogbo igba lo n tele okunrin kan eleyii ti kii se oko re. Awon kan tile tun jeri wi pe, oseese ki maanu naa ti ...

Read More »

Kini ero yin nipa awon obirin to ga fiofio?

Mo mo wi pe awon obirin maa n fe lati fe awon okunrin to ba ga. Sugbon mi o mo boya bakan naa lori pelu awon okunrin nipa fiferan awon obirin to ga fiofio. Se kii se wi pe giga ...

Read More »

Aregbesola sedaro Hon. Makinde to doloogbe

Gomina ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ti ranse ibanikedun si idile Hon Makinde Oladejo Samson to doloogbe lojo Aiku to koja yii, 27/12/15. Hon Makinde, omo egbe PDP, to je okan lara awon omo ile igbimo asofin ipinle Osun lo ...

Read More »

Odun Iwude Ijesa: Gbogbo aye pejo saafin Owa Obokun

Ese ko gbero lojo Satide to koja yii niluu Ilesa nibi ti tonile talejo ti gbe pejo lati sodun Iwude Ijesa laafin Owa Obokun Adimula ti ile Ijesa, Oba Gabriel Adekunle Aromolaran. Gege bi a se gbo, ayeye odun Iwude ...

Read More »