Home / Àṣà Oòduà (page 120)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Se e ti gbo nipa Beewealth-Textiles?

Arambara aso oge mbe lowo Beewealth-Textiles!  

Read More »

“Efon ti n fa kokoro Zika wa ni Naijiria, kosi ti gboogun”- Minisita Ilera

Minisita fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole, ti se idaniloju alaye wi pe, efon abami ti n sokunfa kokoro Zika ti ko gboogun ti wa ni Naijiria. Bakan naa lo si ro awon eniyan lati se ohun gbogbo ni ikapa ...

Read More »

Bayii ni Jumoke Orisaguna omo oniburedi se di oloriire

Awon foto re wa nisale

Read More »

“Ijoba etan ati jaguda ni Mimiko n se nipinle Ondo” – APC

*Mimiko ya bilionu meedogun soto lati san gbese Lose to koja ni awuyewuye kan tun seyo nipinle Ondo nigba ti egbe oselu APC tako Gomina Olusegun Mimiko ti ipinle naa nipa bo se ya bilionu meedogun ati milionu mejo (N15. ...

Read More »

Bayii ni a se le se iwosan fun eni to ni kokoro inu eje

Awon ohun elo ti a gbodo wa ni yii:   1 Omi osan wewe igo kan tabi oti igo kan tabi omi grape igo kan 2 Capsule red & yellow eyo mewaa (10 pieces) 3 Ewe taba ti won ti ...

Read More »

Ewu to wa ninu foonu lilo ati pataki ilera wa

Opolopo wa ni a n lo foonu ni aye ode oni, sugbon ti a kosi mo awon ewu keekeke to ro mo o eleyii to le se ipalara fun ago ara wa. E je ka ri daju wi pe a ...

Read More »

Kini okunrin le se to le mu iyawo re se iru idajo bayii fun

Omobirin yii lo fi ja nnkan omokunrin oko re sonu patapata.

Read More »

Iwosan ogbe inu

Awon nnkan won yii lo maa n se okunfa ogbe inu; ki eniyan maa fi ebi pa ara re nigba gbogbo, jije ounje gbigbona ati iyo pupo ninu ounje ati bee bee lo. Bi a se maa se iwosan naa ...

Read More »

E jowo eyin, abiyamo, e dakun e gba wa ni imoran ..

OOOOOOO Oro naa ti di lbanuje ati edun okan fun molebi mi, e dakun e gba mi ooooo. Mo je Omo odun metadinlogbon (27 years) Taiwo. . . . . . ni Oruko mi, Okunrin ni mi, bakan naa ni ...

Read More »

Awon agbejoro tuntum ti ogbeni saraki sese GBA ni yi o

Ejowo kini oruko won ?

Read More »