Home / Iroyin Pajawiri (page 124)

Iroyin Pajawiri

Iwo taa lo gbeja ninu awon meteeta?

Iwo taa lo gbeja ninu awon meteeta?

Read More »

Buruji Kashamu je gbese! Ile ejo ti fagile eto idibo to gbe wole gege bi senator

Ile ejo ti fagile eto idibo to gbe Senator Buruji Kashamu wole sile igbimo asofin agba Abuja lati soju Ogun. Won ni magomago po ninu eto idibo naa, ati wi pe won yoo tun ibo naa di ni.

Read More »

Ahmed (Amedi) Musa lo rawon julo bayii niluu Russia

Ogbontarigi agbaboolu omo Naijiria, Ahmed Musa, ti n le waju bayii ninu awon agbaboolu to rawon julo niluu Russia.  Iroyin yii jade ni kete ti egbe agbaboolu re, CSKA Moscow jawe olubori nigba ti won pade pelu Dynamo pelu ayo ...

Read More »

Ohun to mu Odun Ominira eyi yato si ti igba ti Goodluck Jonathan wa lori oye

Ara opo awon omo Naijiria tun ya gaga si orile ede won lojo Alamisi to koja, nigba ti a se ayeye ominira odun karunlelaadota. Kaakiri awon ipinle, opo eniyan lo ki akegbe won ku oriire, ti won si n soro ...

Read More »

Se N’Ibadan Tia Nile Oluyole?

Ibadan tia! Se n’Ibadan tia? Ibo lawa o mo lOluyole Ibadan? MAPO d’AYẸYẸ Gbogbo ODÍNJÓ tia ni, ELEKURỌ, ALEKUSỌ, Ibo gan-an lawa o mo n’Ibadan? BẸRẸ titi to fi de ÒÓPÓ Yoosa, Ibi to ku taa mo ni ke e ...

Read More »

Tai Solarin Dilu Nla

Tai Solarin dilu nla Tai Solarin ile ẹkọ nla to dilu nla. Ibi ọgbọn gbe pamọ si. Arọni imọ ti n ja ni laya bi oke. Gbékanlùkan isẹ ọpọlọ to fakíki. Kinihun o jẹran ikaṣi. To ba jọ bi irọ, ...

Read More »

Olopaa Ko Le Mu…

Okan lara awon aworan to jade lati ipinle Bauchi sori ayelukara lojo odun ileya to koja ni yii.  Lotito, olopaa ko le mu won. Nitori olopaa kan wo won lotito ko si le da won duro. Sebi odun lo de.

Read More »

Kilode Ti Ogbeni Bukola Saraki Fi N Paro?: O paro Nile Ejo Tiribuna, O Tun Paro Fun Omo Naijeria

Ni ile Yorubawa, ti omo kekere ba n paro, awon agba gba wi pe iru omo naa le jale tabi ko ti maa jale. Lara esun metala ti eka onidajo ti Code of Conduct Bureau, Code of Conduct Tribunal gbe ...

Read More »

Ohun Ti E Ko Mo Nipa Igbeyawo Obasanjo Ati Iyawo Re, Mama Iyabo

Ki e to tesiwaju lati ka abala keji iroyin yii, maa royin ki e ka abala kinni na. Eleyii yoo fun yin ni oye ibi ti alaye naa ti bere. E le ka iroyin naa ninu linki isale yii: Bi ...

Read More »

Hannah Idowu Dideolu Awolowo Ti Lo Ba Oko Re Lorun

Won ti bere igbaradi, inu osu kokanla odun yii ni won pinnu lati se ojo ibi Ogorun (100) Odun Yeye Oodua. Sugbon iku seka, iku doro, iku mu Hannah Idowu Dideolu Awolowo lo leni odun mokandinlogorun (99).   Ki Edua oke ...

Read More »