Home / Iroyin Pajawiri (page 91)

Iroyin Pajawiri

Ogboni – Isese Lagba

EEPA MOLE !!!

Read More »

ARUGBA is no longer a Virgin maid

Arugba is not only seen as a virgin maid any longer, she is regarded a goddess herself and people make prayers and cast all their problem on her as she bears the calabash and passes on to lead the people ...

Read More »

Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni Oba méjì, Ifá to Oba o, Òrúnmìlà ni Baba wa, Ifá to Oba o.

Oriki  to Orunmila Ifá Olókun, A – sorò – dayò, Elérìn-ìpin, Ibìkejì Èdùmàrè. The Diviner of the Sea, the one who makes affairs prosper, Witness to Creation, Second to the Creator. Òrúnmìla ni Baba wa o e, àwa kò ni ...

Read More »

Odu ifa IWORI MEJI

| | | |  |    |  |    | | | | |  Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi opin ose, emin wa yio se pupo re laye ase. Odu ifa IWORI MEJI lo gate laaro yi, ...

Read More »

Odu ifa OYEKU MEJI

|| || || || || || || || Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Oni a san wa o ase. Odu ifa to gate laaro yi ni OYEKU MEJI, ifa yi gba akapo ti odu ifa yi ba jade si ...

Read More »

Odu Ifa Owonrinpota/ Osa

| |  | | | |   |  |     |  |     | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi ana, a sin ku imura ise oni, Eledumare yio jeki ose yi je ose ayo ati ...

Read More »

Odu Ifa Owonrinwese/ Owonrin Ose

| |   |  | |  | |  |    | | |   |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a si ku ola jimoh oni emi wa yio se pupo re laye o, ...

Read More »

Tale Feran Ju Ninu K1 Ati Ksa

Read More »

Ogulutu Oro Toni 18.08.2016

Hummmmmm ohun ta nfe la ndaso bo koseni tio mope irun ori poju irun ibikan lo ‪woo orewa‬ Nje o mope ohun taba gbe pamo ni I niyi? Moraso ogun mofi han eyan ogbon hummmmmm. ‎gbomi dada‬ Bisu eni bata ...

Read More »

Odu Ifa Owonrin Elejigbo/ Otua

| |  | | | | | |    | |    | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku imura toni, mo gbaladura wipe bi a se njade lo laaro yi aori ...

Read More »