Home / Àṣà Oòduà / ‪Laye Atijo: Opo Sisu (Nje o dara lati maa supo?)

‪Laye Atijo: Opo Sisu (Nje o dara lati maa supo?)

Ni akoko, mo sure fun toko-taya pe iku aitojo ko ni pa gbogbo wa o(ASE EDUMARE).
……..
Ni aye atijo, ti oko ba tete ku, ti iyawo re si tun wa loju-opon, won o ba so pe ki aburo oko su u lopo; to ba si je wipe omo iyaale kan nbe to to iyawo yii fe, won o so pe oun ni ko su u lopo.
………..
PATAKI OPO SISU
Ki Opo yii ma baa se maa yan ale, ati ko le maa toju awon omo re ni akata molebi yii.
…….
‪#‎IBEERE‬ :
1 Nje o dara lati maa supo?
2 Anfaani wo lo wa nibe?
3 Aleebu wo lo wa nibe?

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo