Home / Àṣà Oòduà / ‪#‎Gbagede Asa-19/03/2016

‪#‎Gbagede Asa-19/03/2016

Omo Oduduwa, Olodumare jogun awo to rewa fun wa; awo dudu ni gbogbo aye mo iran wa si, bo sie je wipe alawo pupa die naa nbe ninu-un wa.
…….
Ewa n be lara awo dudu, nitori awa gan ni adumaradan; A dudu bii koro isin. Adiagbon, osun ati oori lawon obi wa fi maa n para laye atijo; won si maa n kun atike; ti laali lile naa ko si gbeyin.
…….
‪#‎IBEERE‬ :

1 Kinni eyin lero wipe o faa ti awon omo ode oni fi n bora?
2 Nje o bojumu bi?

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo