Home / Àṣà Oòduà / Iwure Owuro 27/03/2016

Iwure Owuro 27/03/2016

::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::
E MAA WI TELE MI :
………
*Edumare ma fi omo pa mi lekun.
*Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun.
*Ogun aye koni bori mi.
*Iji aye koni ja lu mi.
*Inira ati idaamu, koni je temi.
*Aye koni so mi mole bi eran iso.
*Omi aye koni gbe mi lo(Ase).
………..
‪#‎OLUWURE‬ : Iyalode Olusola Arike Ola

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo