Home / Àṣà Oòduà / Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin

Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin

Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala arun oju patapata. Bi a se le se itoju iru oju naa ni yii:
Oyin gidi ati ogeere epo pupa ni a o da papo mora won. Eni naa yoo maa mu sibi-ijeun meji leemeta lojumo – aaro, osan ati lale.
Yato si eleyii, eni naa gbodo maa je karoti (carrot) ati jije water melon pelu eepo re papo. Eni naa yoo se eleyii fun odin-indi osu kan.
Pelu ogo Olorun, oju naa yoo kilia bi oju omo tuntun ti yoo si ma riran kedere bi osupa.
Olayemi Alagbo n ki yin ooo!
E ku ikale!
Olayemioniroyin.com

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?