Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi won ti n dana fiimu tuntun.

Tagged with: Àṣà Yorùbá