Tag: Àṣà Yorùbá
-
È má jé kì olá èro ayélujára tàn yín je- báyìí ni Joke Silva wí.
Nínú ìfòròwánilénuwò nínú ìwé ìròyìn ti Genevieve Nnaji tí won se fún ognóntàrigì òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Joke Silva, ni ó ti gba àwon èèyàn ní ìmòràn kí won má se jé kí ohun tí àwon elégbé òhun máa n pín sí orí ìtàgé tàn wón je, nítorí òpò nínú won ni…
-
Àwòrán Ìlú Abeokuta nígbà tí a wò ó láti orí òkè olúmo (olumo rock).
Òkè olúmo jé òkè kan gbòógì tí a kò le fi owó ró séyìn nínú àwon òkè tí n be ní orílè èdè Nìjíríà, kìí wá se orílè èdè yí nìkan ni a kò tile fi owó ro séyìn bí kò se wípé káàkiri ilè Adúláwò. Orí òkè yí ni àwon kan wà tí won…
-
Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná.
Àwon àjo tí ó n mójú tó ètò ìdìbó tí a mò sí INEC ti kéde Gboyega Oyetola gégé bí eni tí ó gbégbà orókè níbi ìdìbò tí won tún dì ní àná. Omo egbé oní ìgbálè tí won fà kalè láti lo fún Gómìnà, egbé tí a mò sí APC ti yan Gboyega Oyetola…
-
Òrò ìsítí gbó òréëwa?
Òrò ìsítí gbó òréëwa? -O féékú wàákú, Ìwõ ò fèékú wàákú sugbon kini kan lèmi fë kio mø daju, Sé nigba tó o wásí ile-aye sé kii sepé àrà(Wonder) ku mó ë ninu. Àrà tóò gbéwá silé ayé tóò ló, tíò “manifest ninu aye rë tawön eniyan o ” benefit ninu rë, tóo bá kú…
-
E ku Ose Sango
Igba ara lanbura enikan kinbu sango lerun adifafun olukoso laalu arabambi Omo arigba ota Segun onbelarin ota onfi ojo jumo konminu ajogun…Tani Peri oba to oo Emi oo operire alade..Sango yiobawa Segun gbogbo Otawa aori tiwase.E ku ose sango, Ase Edumare.. AWO OSA LOGBE.
-
Òtúrá Òfún (Òtúráfùnún)
Àkúsàba Àyàndà Awo ilé Olúmẹ̀ri Àápáálá Ọmọ ilé san wón ó joko lọ Níjọ́ tí ń ṣọ̀gbọ̀gbọ̀ àrùn Tí ń najú aláì le dìde Olúmẹ̀ri Àápáálá làrùn ń ṣe Òún wá á le gbádùn gbogbo nǹkan òun lójú ayé òun báyìí? Wọ́n ní ewúrẹ́ kan ni kó rú Ó rú ewúrẹ́ kan Wọ́n ṣe Ifá…
-
Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè.
Àwòrán ará ilé Bbnaija télè tí a mò sí Alex, ìyá rè àti ìyá ìyá rè. Alex Asogwa pín àwòrán rè tí ó rewà àti ti ìyá rè àti ìyá ìyá rè tí ó rewà, ìran méta tí ó rewà púpò. Àwòrán yí mà rewà púpò, ìran méta yí sì wuni púpò jù.
-
Omokùnrin odún métàlá (13) ni àwon olópàá ti mú látàrí ìbèrú tí ó ní sí won.
Omokúnrin kékeré kan ní won ti mó’ lé ní àgó olópàá látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá. Gégé bí ìròyìn se so, omokùnrin odún métàlá, tí ó sí jé olórí okúnrin ilé-èkó won, ni ó n pon omi lówó nínú kànga ní iwájú ilé won, nígbà tí ó rí àwon oní jàgídíjàgan ní…
-
Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter
Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè Eko. Bákan náà, won tún sí ojú olú polówó ojà won tí a mò sí…
-
Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.
Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná. Ààre ilé ìgbìmò Asòfin tí a mò sí Dókítà Abubakar Bukola Saraki ní àná tí lo kí omo egbé oní àbùradà tí a mò sí egbé PDP, èyí tí egbé yàn láti lo fún Gómìnà ìpínlè won ní Osun, Seneto Ademola Adeleke tí ìlú…